Isaías 54

YOR

1 “Kọrin, ìwọ obìnrin àgàn,

2 Fẹ ibi àgọ́ rẹ lójú sí i,

3 Nítorí ìwọ ó fẹ̀ sọ́tùn àti sí òsì;

4 “Má ṣe bẹ̀rù, ìtìjú kò ní ṣubú lù ọ́.

5 Nítorí Ẹlẹ́dàá rẹ ni ọkọ rẹ

6 Olúwa yóò pè ọ́ padà

7 “Fún ìgbà díẹ̀ ni mo kọ̀ ọ́ sílẹ̀,

8 Ní ríru ìbínú.

9 “Sí mi, èyí dàbí i àwọn ọjọ́ Noa,

10 Bí a tilẹ̀ mi àwọn òkè ńlá

11 Ìwọ ìlú tí a pọ́n lójú, tí ìjì ń gbá kiri

12 Èmi yóò fi iyùn ṣe odi rẹ,

13 Gbogbo ọ̀dọ́mọkùnrin rẹ ni Olúwa yóò kọ́,

14 Ní òdodo ni a ó fi ìdí rẹ kalẹ̀

15 Bí ẹnikẹ́ni bá tilẹ̀ bá ọ jà, kò ní jẹ́ láti ọwọ́ mi;

16 “Kíyèsi i, èmi ni ó dá alágbẹ̀dẹ

17 kò sí ohun ìjà tí a ṣe sí ọ tí yóò lè ṣe nǹkan,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado