Isaías 52

YOR

1 Jí, jí, ìwọ Sioni,

2 Gbọn eruku rẹ kúrò;

3 Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí,

4 Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa Olódùmarè wí.

5 “Àti ní àkókò yìí, kí ni mo ní níbí?” ni Olúwa wí.

6 Nítorí náà àwọn ènìyàn mi yóò mọ orúkọ mi;

7 Báwo ni ó ṣe dára tó lórí òkè

8 Tẹ́tí sílẹ̀! Àwọn olùṣọ́ rẹ gbé ohùn wọn sókè

9 Ẹ bú sí orin ayọ̀ papọ̀,

10 Olúwa yóò ṣí apá mímọ́ rẹ̀ sílẹ̀

11 Ẹ túká, ẹ túká, ẹ jáde kúrò níhìn-ín yìí!

12 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kì yóò yára kúrò

13 Kíyèsi i, ìránṣẹ́ mi yóò hùwà ọlọ́gbọ́n;

14 Gẹ́gẹ́ bí a ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n ń bu ọlá fún un—

15 Bẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe bomirin àwọn orílẹ̀-èdè ká,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado