Isaías 51

YOR

1 “Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin tí ó ń lépa òdodo

2 ẹ wo Abrahamu baba yín,

3 Dájúdájú, Olúwa yóò tu Sioni nínú

4 “Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin ènìyàn mi;

5 Òdodo mi ń bọ̀ wá kíkankíkan,

6 Gbé ojú rẹ sókè sí àwọn ọ̀run,

7 “Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin tí ó mọ ohun òtítọ́,

8 Nítorí kòkòrò yóò mú wọn lá bí aṣọ,

9 Dìde, dìde! Kí o sì wọ ara rẹ ní agbára

10 Ìwọ kọ́ ni ó gbẹ omi Òkun bí

11 Àwọn ẹni ìràpadà Olúwa yóò padà wá.

12 “Èmi, àní Èmi, èmi ni ẹni tí ó tù ọ́ nínú.

13 tí ìwọ sì gbàgbé Olúwa ẹlẹ́dàá rẹ,

14 Àwọn ẹlẹ́wọ̀n tí ń ṣojo la ó dá sílẹ̀ ní àìpẹ́ jọjọ

15 Nítorí Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ,

16 Mo ti fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ

17 Jí, jí!

18 Nínú gbogbo ọmọ tí ó bí

19 Àjálù ìlọ́po ìlọ́po yìí ti dé bá ọ—

20 Àwọn ọmọkùnrin rẹ ti dákú;

21 Nítorí náà ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí a ti ṣẹ́ níṣẹ̀ẹ́,

22 Ohun tí Olúwa Olódùmarè yín wí nìyìí,

23 Èmi yóò fi lé àwọn apọ́nilójú rẹ lọ́wọ́,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado