Isaías 50

YOR

1 Ohun tí Olúwa wí nìyìí:

2 Nígbà tí mo wá, èéṣe tí a kò fi rí ẹnìkan?

3 Èmi fi òkùnkùn bo sánmọ̀

4 Olúwa Olódùmarè ti fún mi ni ahọ́n tí a fi iṣẹ́ rán,

5 Olúwa Olódùmarè ti ṣí mi ní etí,

6 Mo ṣí ẹ̀yìn mi sílẹ̀ fún àwọn tí ó ń nà mí,

7 Nítorí Olúwa Olódùmarè ràn mí lọ́wọ́,

8 Ẹni tí ó dá mi láre wà nítòsí.

9 Olúwa Olódùmarè ni ó ń ràn mí lọ́wọ́.

10 Ta ni nínú yín tí ó bẹ̀rù Olúwa

11 Ṣùgbọ́n ní àkókò yìí, gbogbo ẹ̀yin ti ń tanná

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado