Isaías 49

YOR

1 Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin erékùṣù:

2 Ó ṣe ẹnu mi bí idà tí a pọ́n,

3 Ó sọ fún mi pé, “Ìránṣẹ́ mi ni ìwọ í ṣe,

4 Ṣùgbọ́n èmi sọ pé, “Mo ti ṣe wàhálà lórí asán;

5 Nísinsin yìí Olúwa wí pé

6 Òun wí pé:

7 Ohun tí Olúwa wí nìyìí,

8 Ohun tí Olúwa wí nìyìí:

9 láti sọ fún àwọn ìgbèkùn pé, ‘Ẹ jáde wá,’

10 Ebi kì yóò pa wọ́n bẹ́ẹ̀ ni òǹgbẹ kì yóò gbẹ wọ́n,

11 Èmi yóò sọ gbogbo àwọn òkè ńlá mi di ojú ọ̀nà

12 Kíyèsi i, wọn yóò wá láti ọ̀nà jíjìn

13 Ẹ hó fún ayọ̀, ẹyin ọ̀run;

14 Ṣùgbọ́n Sioni sọ pé, “Olúwa ti kọ̀ mí sílẹ̀,

15 “Ǹjẹ́ abiyamọ ha le gbàgbé ọmọ ọmú rẹ̀

16 Kíyèsi i, mo ti kọ ọ́ sí àtẹ́lẹwọ́ mi

17 Àwọn ọmọ rẹ ti kánjú padà,

18 Gbójú rẹ sókè kí o sì wò yíká;

19 “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a tí run ọ́, a sì sọ ọ́ di ahoro

20 Àwọn ọmọ tí a bí ní àkókò ọ̀fọ̀ rẹ

21 Nígbà náà ni ìwọ yóò sọ ní ọkàn rẹ pé,

22 Ohun tí Olúwa Olódùmarè wí nìyìí,

23 Àwọn ọba ni yóò jẹ́ alágbàtọ́ baba fún ọ,

24 Ǹjẹ́ a le gba ìkógun lọ́wọ́ jagunjagun,

25 Ṣùgbọ́n ohun tí Olúwa wí nìyìí:

26 Èmi yóò mú kí àwọn aninilára rẹ̀ jẹ ẹran-ara wọn;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado