Isaías 48

YOR

1 “Tẹ́tí sí èyí, ìwọ ilé e Jakọbu,

2 ìwọ tí ò ń pe ara rẹ ní ọmọ ìlú mímọ́ n nì

3 Èmi sọ àsọtẹ́lẹ̀ àwọn nǹkan ti tẹ́lẹ̀ lọ́jọ́ tó ti pẹ́,

4 Nítorí mo mọ bí ẹ ti jẹ́ olórí kunkun tó;

5 Nítorí náà mo ti sọ nǹkan wọ̀nyí fún ọ

6 Ìwọ ti gbọ́ àwọn nǹkan wọ̀nyí; wo gbogbo wọn.

7 A dá wọn ní àkókò yìí kì í ṣe láti ìgbà pípẹ́

8 Ìwọ a ha ti gbọ́ tàbí ó ti yé ọ bí

9 Nítorí orúkọ ara mi, mo dáwọ́ ìbínú mi dúró;

10 Wò ó, èmi ti tún ọ ṣe, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé

11 Nítorí orúkọ mi, nítorí orúkọ mi, mo ṣe èyí.

12 “Tẹ́tí sí mi, ìwọ Jakọbu

13 Ọwọ́ mi pàápàá ni ó fi àwọn ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,

14 “Gbogbo yín, ẹ péjọ kí ẹ sì gbọ́.

15 Èmi, àní Èmi ló ti sọ̀rọ̀;

16 “Ẹ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi kí ẹ sì dẹtí sí èyí:

17 Èyí ni ohun tí Olúwa wí,

18 Bí ó bá ṣe pé ìwọ bá ti tẹ́tí sílẹ̀ sí àṣẹ mi,

19 Àwọn ọmọ rẹ ìbá ti dàbí iyanrìn,

20 Fi Babeli sílẹ̀,

21 Òrùngbẹ kò gbẹ wọ́n nígbà tí ó kó wọn

22 “Kò sí àlàáfíà,” ni Olúwa wí,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado