1 “Sọ̀kalẹ̀, jókòó nínú eruku,
2 Mú òkúta-ọlọ kí o sì lọ ìyẹ̀fun;
3 Ìhòhò rẹ ni a ó sí síta
4 Olùràpadà wa Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀
5 “Jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, lọ sínú òkùnkùn,
6 Inú bí mi sí àwọn ènìyàn mi
7 Ìwọ wí pé, ‘Èmi yóò tẹ̀síwájú títí láé—
8 “Nísinsin yìí, tẹ́tí sílẹ̀, ìwọ oníwọ̀ra ẹ̀dá
9 Méjèèjì yìí ni yóò wá sórí rẹ
10 Ìwọ ti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ìwà ìkà rẹ
11 Ìparun yóò dé bá ọ
12 “Tẹ̀síwájú nígbà náà, pẹ̀lú àfọ̀ṣẹ rẹ
13 Gbogbo ìmọ̀ràn tí o ti gbà ni
14 Lóòótọ́ wọ́n dàbí ìṣẹ́pẹ́ igi;
15 Gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe fún ọ nìyìí