Isaías 45

YOR

1 “Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún ẹni òróró rẹ̀,

2 Èmi yóò lọ síwájú rẹ,

3 Èmi yóò sì fún ọ ní àwọn ọrọ̀ ibi òkùnkùn,

4 Nítorí Jakọbu ìránṣẹ́ mi

5 Èmi ni Olúwa, àti pé kò sí ẹlòmíràn;

6 tí o fi jẹ́ pé láti ìlà-oòrùn

7 Mo dá ìmọ́lẹ̀, mo sì dá òkùnkùn,

8 “Ìwọ ọ̀run lókè rọ òjò òdodo sílẹ̀;

9 “Ègbé ni fún ènìyàn tí ó ń bá Ẹlẹ́dàá rẹ̀ jà,

10 Ègbé ni fún ẹni tí ó sọ fún baba rẹ̀ pé,

11 “Ohun tí Olúwa wí nìyìí,

12 Èmi ni ẹni tí ó dá ilẹ̀ ayé

13 Èmi yóò gbé Kirusi sókè nínú òdodo mi.

14 Ohun tí Olúwa wí nìyìí:

15 Nítòótọ́ ìwọ jẹ́ Ọlọ́run tí ó fi ara rẹ̀ pamọ́,

16 Gbogbo àwọn tí ó ń gbẹ́ ère ni ojú yóò tì

17 Ṣùgbọ́n Israẹli ni a ó gbàlà láti ọwọ́ Olúwa

18 Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí,

19 Èmi kò sọ̀rọ̀ níbi tí ó fi ara sin,

20 “Ẹ kó ara yín jọ kí ẹ sì wá;

21 Jẹ́ kí a mọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀, fihàn wá,

22 “Yípadà sí mi kí a sì gbà ọ́ là,

23 Nípa èmi tìkára mi ni mo ti búra,

24 Wọn yóò sọ ní ti èmi, ‘Nínú Olúwa nìkan ni

25 Ṣùgbọ́n nínú Olúwa gbogbo àwọn ìran Israẹli

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado