1 Ṣùgbọ́n ní ìsinsin yìí, ohun tí Olúwa wí nìyìí,
2 Nígbà tí ìwọ bá ń la omi kọjá,
3 Nítorí Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ,
4 Nítorí pé o ṣe iyebíye àti ọ̀wọ́n níwájú mi,
5 Má bẹ̀rù nítorí èmi wà pẹ̀lú rẹ;
6 Èmi yóò sọ fún àríwá pé, ‘Fi wọ́n sílẹ̀!’
7 ẹnikẹ́ni tí a ń pe orúkọ mi mọ́,
8 Sin àwọn tí ó ní ojú ṣùgbọ́n tí wọ́n fọ́jú jáde,
9 Gbogbo orílẹ̀-èdè kó ra wọn jọ
10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,” ni Olúwa wí,
11 Èmi, àní Èmi, Èmi ni Olúwa,
12 Èmi ti fihàn, mo gbàlà mo sì ti kéde
13 Bẹ́ẹ̀ ni, àti láti ayérayé Èmi ni ẹni náà.
14 Èyí ni ohun tí Olúwa wí,
15 Èmi ni Olúwa, Ẹni Mímọ́ rẹ,
16 Èyí ni ohun tí Olúwa wí,
17 ẹni tí ó wọ́ àwọn kẹ̀kẹ́ àti ẹṣin jáde,
18 “Gbàgbé àwọn ohun àtẹ̀yìnwá;
19 Wò ó, Èmi ń ṣe ohun tuntun!
20 Àwọn ẹhànnà ẹranko bọ̀wọ̀ fún mi,
21 àwọn ènìyàn tí mo dá fún ara mi
22 “Síbẹ̀síbẹ̀ ìwọ kò tí ì ké pè mí, ìwọ Jakọbu,
23 Ìwọ kò tí ì mú àgùntàn wá fún mi fún ẹbọ sísun,
24 Ìwọ kò tí ì ra kalamusi olóòórùn dídùn fún mi,
25 “Èmi, àní Èmi, Èmi ni ẹni tí ó wẹ
26 Bojú wo ẹ̀yìn rẹ fún mi,
27 Baba yín àkọ́kọ́ dẹ́ṣẹ̀;
28 Nítorí náà, èmi ti sọ àwọn olórí ibi mímọ́ náà di àìmọ́,