Isaías 41

YOR

1 “Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú mi ẹ̀yin erékùṣù!

2 “Ta ni ó ti ru ẹnìkan sókè láti ìlà-oòrùn wá,

3 Ó ń lépa wọn ó sì ń kọjá ní àlàáfíà,

4 Ta ni ó ti ṣe èyí tí ó sì ti jẹ́ kí ó wáyé,

5 Àwọn erékùṣù ti rí i wọ́n bẹ̀rù;

6 èkínní ran èkejì lọ́wọ́

7 Oníṣọ̀nà gba alágbẹ̀dẹ wúrà níyànjú,

8 “Ṣùgbọ́n ìwọ, ìwọ Israẹli, ìránṣẹ́ mi,

9 mo mú ọ láti ìpẹ̀kun ilẹ̀ ayé,

10 Nítorí náà má bẹ̀rù, nítorí èmi wà pẹ̀lú rẹ;

11 “Gbogbo àwọn tí ó bínú sí ọ

12 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ yóò wá àwọn ọ̀tá rẹ,

13 Nítorí Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ,

14 Má ṣe bẹ̀rù, ìwọ Jakọbu kòkòrò,

15 “Kíyèsi, Èmi yóò sọ ọ́ di òòlù ìpakà tuntun,

16 Ìwọ yóò fẹ́ wọn, afẹ́fẹ́ yóò sì gbá wọn mú,

17 “Àwọn tálákà àti aláìní wá omi,

18 Èmi yóò mú kí odò kí ó sàn ní ibi gíga

19 Èmi yóò fi sínú aṣálẹ̀

20 tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ènìyàn yóò fi rí i tí wọn yóò sì fi mọ̀,

21 “Mú ẹjọ́ wá,” ni Olúwa wí.

22 “Mú àwọn ère òrìṣà rẹ wọlé láti sọ fún wa

23 ẹ sọ fún wa ohun ti ọjọ́ iwájú mú dání

24 Ṣùgbọ́n ẹ̀yìn ko jásí nǹkan kan

25 “Èmi ti ru ẹnìkan sókè láti àríwá, òun sì ń bọ

26 Ta ni ó sọ èyí láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, tí àwa kò bá fi mọ̀,

27 Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó sọ fún Sioni pé, ‘Wò ó, àwọn nìyìí!’

28 Èmi wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan—

29 Kíyèsi i, irọ́ ni gbogbo wọn!

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado