Isaías 33

YOR

1 Ègbé ni fún ọ, ìwọ apanirun,

2 Olúwa ṣàánú fún wa

3 Ní ìkérara ohùn rẹ, àwọn ènìyàn sá,

4 Ìkógun rẹ, ìwọ orílẹ̀-èdè ni a kórè

5 A gbé Olúwa ga, nítorí pé ó ń gbé ibi gíga,

6 Òun yóò jẹ́ ìpìlẹ̀ tí ó dájú fún àkókò rẹ

7 Wò ó, àwọn onígboyà ọkùnrin wọn pohùnréré

8 Àwọn ojú ọ̀nà ńlá ni a ṣá tì,

9 Ilẹ̀ ṣọ̀fọ̀ ó sì ṣòfò dànù,

10 “Ní ìsinsin yìí ni èmi yóò dìde,” ni Olúwa wí.

11 Ìwọ lóyún ìyàngbò,

12 A ó jó àwọn ènìyàn run bí eérú;

13 Ìwọ tí ó wà lọ́nà jíjìn, gbọ́ ohun tí mo ti ṣe;

14 Ẹ̀rù ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní Sioni;

15 Ẹni tí ó ń rìn lódodo

16 Òun náà yóò gbé ní ibi gíga,

17 Ojú rẹ yóò rí ọba nínú ẹwà rẹ̀

18 Nínú èrò rẹ ìwọ yóò rántí ẹ̀rù rẹ àtẹ̀yìnwá:

19 Ìwọ kì yóò rí àwọn agbéraga ènìyàn mọ́,

20 Gbójú sókè sí Sioni, ìlú àjọ̀dún wa,

21 Níbẹ̀ ni Olúwa yóò ti jẹ́ alágbára kan fún wa.

22 Nítorí Olúwa ni onídàájọ́ wa,

23 Gbogbo okùn rẹ ni ó ti dẹ̀:

24 Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó ń gbé Sioni tí yóò wí pé, “Ara mi kò yá,”

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado