1 Súnmọ́ tòsí,
2 Nítorí ìbínú Olúwa ń bẹ
3 Àwọn ti a pa nínú wọn
4 Gbogbo àwọn ogun ọ̀run ni yóò di yíyọ́,
5 Nítorí ti a rẹ idà mi ní ọ̀run,
6 Idà Olúwa kún fún ẹ̀jẹ̀
7 Àti àwọn àgbáǹréré yóò
8 Nítorí ọjọ́ ẹ̀san Olúwa ni,
9 Odò rẹ̀ ni a ó sì sọ di ọ̀dà,
10 A kì yóò pa á ní òru tàbí ní ọ̀sán;
11 Òwìwí aginjù, àti àkàlà ni yóò ni ín,
12 Ní ti àwọn ìjòyè rẹ̀
13 Ẹ̀gún yóò sì hù jáde
14 Àwọn ẹranko ijù àti àwọn ìkookò ni yóò pàdé,
15 Òwìwí yóò tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ síbẹ̀,
16 Ẹ wo ìwé Olúwa, kí ẹ sì kà.
17 Ó ti di ìbò fún wọn,