Isaías 28

YOR

1 Ègbé ni fún adé ìgbéraga,

2 Kíyèsi i, Olúwa ní ẹnìkan tí ó le, tí ó sì lágbára,

3 Adé ìgbéraga àwọn ọ̀mùtí Efraimu,

4 Òdòdó tí ó ń rọ náà tí í ṣe ẹwà ògo rẹ̀,

5 Ní ọjọ́ náà Olúwa àwọn ọmọ-ogun

6 Òun yóò sì jẹ́ ẹ̀mí ìdájọ́ òdodo

7 Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n fún ọtí wáìnì

8 Gbogbo orí tábìlì ni ó kún fún èébì

9 “Ta ni ẹni náà tí ó ń gbìyànjú àti kọ́?

10 Nítorí tí í ṣe: báyìí ni orí,

11 Ó dára báyìí, pẹ̀lú ètè àjèjì àti ahọ́n àìmọ̀

12 àwọn tí ó sọ fún wí pé,

13 Fún ìdí èyí, ọ̀rọ̀ Olúwa sí wọn yóò di pé,

14 Nítorí náà, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, ẹ̀yin ẹlẹ́gàn,

15 Ẹ fọ́n pé, “Àwa ti bá ikú mulẹ̀,

16 Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí:

17 Èmi yóò fi ìdájọ́ ṣe okùn òsùwọ̀n

18 Májẹ̀mú yín tí ẹ bá ikú dá ni a ó fa igi lé;

19 Nígbàkígbà tí ó bá ti wá ni

20 Ibùsùn kúrú púpọ̀ fún ìnara lé lórí,

21 Olúwa yóò dìde sókè gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe

22 Ní ìsinsin yìí ẹ dákẹ́ ẹlẹ́yà ṣíṣe,

23 Tẹ́tí kí o sì gbọ́ ohùn mi,

24 Nígbà tí àgbẹ̀ kan bá tu ilẹ̀ láti gbìn

25 Nígbà tí òun bá ti tẹ́ ojú ilẹ̀ rẹ̀ pẹrẹsẹ

26 Ọlọ́run rẹ̀ tọ́ ọ ṣọ́nà

27 Nítorí a kò fi ohun èlò ìpakà dili,

28 A gbọdọ̀ lọ ìyẹ̀fun kí a tó ṣe àkàrà;

29 Gbogbo èyí pẹ̀lú ti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wá,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado