Isaías 29

YOR

1 Ègbé ni fún ọ, Arieli, Arieli,

2 Síbẹ̀síbẹ̀ èmi yóò dó ti Arieli

3 Èmi yóò sì wà ní bùba yí ọ ká níbi gbogbo,

4 Ní ìrẹ̀sílẹ̀, ìwọ ó sì máa sọ̀rọ̀ láti ilẹ̀ wá;

5 Ṣùgbọ́n àwọn ọ̀tá rẹ, yóò dàbí yanrìn kíkúnná,

6 Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò wá

7 Lẹ́yìn náà,

8 àti bí ìgbà tí ẹni tí ebi ń pa ń lá àlá pé òun ń jẹun,

9 Ẹ bẹ̀rù kí ẹnu kí ó yà yín,

10 Olúwa ti mú oorun ìjìká wá sórí i yín:

11 Fún un yín gbogbo ìran yìí kò yàtọ̀ sí àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi èdìdì dì sínú ìwé kíká. Bí ẹ bá sì fún ẹni tí ó lè ka ìwé kíká náà, tí ẹ sì sọ fún un pé, “Jọ̀wọ́ ka èyí,” òun yóò dáhùn pé, “Èmi kò lè kà á; a ti dì í ní èdìdì.”

12 Tàbí bí ẹ bá fún ẹni tí kò lè ka ìwé kíká náà tí ẹ sì sọ pé, “Jọ̀wọ́ ka èyí,” òun yóò dáhùn pé, “Èmi kò mọ̀ ọ́n kà.”

13 Olúwa wí pé:

14 Nítorí náà lẹ́ẹ̀kan sí i èmi yóò ya

15 Ègbé ni fún àwọn tí ó lọ sí ọ̀gbun

16 Ẹ̀yin dojú nǹkan délẹ̀,

17 Ní àìpẹ́ jọjọ, ǹjẹ́

18 Ní ọjọ́ náà adití yóò gbọ́ ọ̀rọ̀ ìwé kíká náà,

19 Lẹ́ẹ̀kan sí i àwọn onírẹ̀lẹ̀ yóò yọ̀ nínú Olúwa:

20 Aláìláàánú yóò pòórá,

21 àwọn tí wọ́n fi ọ̀rọ̀ kan mú ẹnìkan di ẹlẹ́bi,

22 Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa, ẹni tí ó ra Abrahamu padà sọ sí ilé Jakọbu:

23 Nígbà tí wọ́n bá rí i láàrín àwọn ọmọ wọn,

24 Gbogbo àwọn tí ń rìn ségesège ní yóò jèrè ìmọ̀;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado