1 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Tire.
2 Dákẹ́ jẹ́ẹ́, ẹ̀yin ènìyàn erékùṣù
3 Láti orí àwọn omi ńlá
4 Kí ojú kí ó tì ọ́, ìwọ Sidoni àti ìwọ
5 Nígbà tí ọ̀rọ̀ bá dé Ejibiti,
6 Kọjá wá sí Tarṣiṣi;
7 Ǹjẹ́ èyí náà ni ìlú àríyá yín,
8 Ta ló gbèrò èyí sí Tire,
9 Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti ṣètò rẹ̀,
10 Tu ilẹ̀ rẹ gẹ́gẹ́ bí i ti ipadò odò Ejibiti,
11 Olúwa ti na ọwọ́ rẹ̀ jáde sí orí Òkun
12 Ó wí pé, “Kò sí àríyá fún ọ mọ́,
13 Bojú wo ilẹ̀ àwọn ará Babeli,
14 Hu, ìwọ ọkọ̀ ojú omi Tarṣiṣi;
15 Ní àkókò náà a ó gbàgbé Tire fún àádọ́rin ọdún, ọjọ́ ayé ọba kan. Ṣùgbọ́n ní òpin àádọ́rin ọdún wọ̀nyí, yóò ṣẹlẹ̀ sí Tire gẹ́gẹ́ bí orin àgbèrè:
16 “Mú dùùrù kan, rìn kọjá láàrín ìlú,
17 Ní òpin àádọ́rin ọdún náà, Olúwa yóò bá Tire jà. Òun yóò sì padà sí àyálò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí panṣágà, yóò sì máa ṣe òwò rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ ọba tí ó wà ní ilẹ̀ ayé.
18 Síbẹ̀síbẹ̀ èrè rẹ̀ àti owó iṣẹ́ rẹ̀ ni a ó yà sọ́tọ̀ fún Olúwa; a kò ní kó wọn pamọ́ tàbí kí a há wọn mọ́wọ́. Ère rẹ̀ ni a ó fi fún àwọn tí ó ń gbé níwájú Olúwa, fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ àti aṣọ.