1 Àsọtẹ́lẹ̀ tí wòlíì Habakuku rí.
2 Olúwa, èmi yóò ti ké pẹ́ tó fún ìrànlọ́wọ́,
3 Èéṣe tí ìwọ fi mú mi rí àìṣedéédéé?
4 Nítorí náà, òfin di ohun àìkàsí,
5 “Ẹ wo inú àwọn kèfèrí, ki ẹ sí wòye,
6 Nítorí pé, èmi yóò gbé àwọn ara Babeli dìde,
7 Wọn jẹ́ ènìyàn ti a bẹ̀rù, tí a sì páyà,
8 Ẹṣin wọn yára ju ẹkùn lọ,
9 gbogbo wọn sì wà fún ìwà ipá
10 Wọn ó si máa fi àwọn ọba ṣẹ̀sín
11 Nígbà náà ni inú rẹ̀ yóò yípadà,
12 Olúwa, ǹjẹ́ láti ayérayé kọ ni ìwọ tí wà?
13 Ojú rẹ mọ́ tónítóní láti wo ibi;
14 Ìwọ sì tí sọ ènìyàn di bí ẹja inú Òkun,
15 Àwọn ènìyàn búburú fi àwọ̀n wọn gbé wọn sókè
16 Nítorí náà, ó rú ẹbọ sí àwọ̀n rẹ̀,
17 Ǹjẹ́ wọn yóò ha máa pa àwọ̀n wọn mọ́ ní òfìfo bí,