Cânticos 8

YOR

1 Ìwọ ìbá rí bí arákùnrin mi si mi,

2 Èmi ìbá fi ọ̀nà hàn ọ́

3 Ọwọ́ òsì rẹ ìbá wà ní abẹ́ orí mi,

4 Ọmọbìnrin Jerusalẹmu, èmi pè yín ní ìjà.

5 Ta ni ẹni tí ń gòkè bọ̀ wá láti aginjù,

6 Gbé mi sí àyà rẹ bí èdìdì

7 Omi púpọ̀ kò le paná ìfẹ́;

8 Àwa ní arábìnrin kékeré kan,

9 Bí òun bá jẹ́ ògiri,

10 Èmi jẹ́ ògiri,

11 Solomoni ní ọgbà àjàrà kan ní Baali-Hamoni

12 Ṣùgbọ́n ọgbà àjàrà mi jẹ́ tèmi, ó wà fún mi;

13 Ìwọ tí ń gbé inú ọgbà,

14 Yára wá, Olùfẹ́ mi,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado