1 Báwo ni ẹsẹ̀ rẹ ti ní ẹwà tó nínú bàtà.
2 Ìdodo rẹ rí bí àwo
3 Ọmú rẹ rí bí abo egbin méjì
4 Ọrùn rẹ rí bí ilé ìṣọ́ eyín erin.
5 Bí òkè Karmeli ṣe ṣe adé yí àwọn òkè ká,
6 Báwo ni ẹwà rẹ ti pọ̀ tó
7 Ìdúró rẹ rí bí igi ọ̀pẹ,
8 Mo ní, “Èmi yóò gun igi ọ̀pẹ lọ,
9 Àti ìfẹnukonu rẹ rí bí ọtí wáìnì tí ó dára jùlọ.
10 Ti olùfẹ́ mi ni èmi í ṣe,
11 Wá, olùfẹ́ mi, jẹ́ kí a lọ sí ibi pápá,
12 Jẹ́ kí a lọ sínú ọgbà àjàrà ní kùtùkùtù
13 Àwọn èso mándrákì mú òórùn wọn jáde