1 Mo rí Olúwa, ó dúró ní ẹ̀bá pẹpẹ, ó sì wí pé:
2 Bí wọ́n tilẹ̀ wa ilẹ̀ lọ sí ipò òkú,
3 Bí wọ́n tilẹ̀ fi ara wọn pamọ́ ni orí òkè Karmeli,
4 Bí wọ́n tilẹ̀ lọ sí ìgbèkùn ní iwájú àwọn ọ̀tá wọn
5 Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun,
6 Òun ni ẹni tí ó kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ nínú àwọn ọ̀run
7 “Àbá ẹ̀yin ọmọ Israẹli
8 “Dájúdájú, ojú Olúwa Olódùmarè
9 “Nítorí Èmi yóò pàṣẹ,
10 Gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ láàrín àwọn ènìyàn mi
11 “Ní ọjọ́ náà ní
12 kí wọn le jogún ìyókù Edomu
13 “Ọjọ́ náà ń bọ,” ni Olúwa wí,
14 Èmi yóò si tún mú ìgbèkùn Israẹli ènìyàn mi padà bọ̀.
15 Èmi yóò gbin Israẹli sí orí ilẹ̀ rẹ̀.