Obadias 1

YOR

1 Ìran ti Obadiah.

2 “Kíyèsi i, Èmi yóò sọ ọ́ di kékeré láàrín àwọn kèfèrí;

3 Ìgbéraga àyà rẹ ti tàn ọ́ jẹ,

4 Bí ìwọ tilẹ̀ gbé ara rẹ ga bí ẹyẹ idì,

5 “Bí àwọn olè tọ̀ ọ́ wá,

6 Báwo ni a ṣe ṣe àwárí nǹkan Esau,

7 Gbogbo àwọn ẹni ìmùlẹ̀ rẹ

8 Olúwa wí pé, “Ní ọjọ́ náà,

9 A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, ìwọ Temani,

10 Nítorí ìwà ipá sí Jakọbu arákùnrin rẹ,

11 Ní ọjọ́ tí ìwọ dúró ní apá kan,

12 Ìwọ kì bá tí fi ojú kéré arákùnrin rẹ,

13 Ìwọ kì bá tí wọ inú ibodè àwọn ènìyàn mi lọ,

14 Ìwọ kì bá tí dúró ní ìkóríta ọ̀nà

15 “Nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ etílé

16 Gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀ ṣe mu lórí òkè mímọ́ mi,

17 Ṣùgbọ́n ìgbàlà yóò wà lórí òkè Sioni,

18 Ilé Jakọbu yóò sì jẹ́ iná

19 Àwọn ará gúúsù yóò ni òkè Esau,

20 Àwọn ìgbèkùn Israẹli tí ó wà ní Kenaani

21 Àwọn tó ń gba ni là yóò sì gòkè Sioni wá

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado