1 Èyí ni ohun tí Olúwa Olódùmarè fihàn mi: agbọ̀n èso pípọ́n.
2 Ó béèrè pé, “Amosi kí ni ìwọ rí.”
3 Olúwa Olódùmarè wí pé, “Ní ọjọ́ náà, àwọn orin tẹmpili yóò yí padà sí ohùn réré ẹkún. Ọ̀pọ̀, àní ọ̀pọ̀ ara òkú ni yóò wà ni ibi gbogbo! Àní ni ìdákẹ́ jẹ́ẹ́!”
4 Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí ń tẹ aláìní lórí ba,
5 Tí ẹ ń wí pé,
6 kí àwa lè fi fàdákà ra àwọn tálákà,
7 Olúwa ti fi ìgbéraga Jakọbu búra pé, “Èmi kì yóò gbàgbé ọ̀kan nínú ohun tí wọ́n ṣe.
8 “Ǹjẹ́ ilẹ̀ náà kì yóò ha wárìrì fún èyí?
9 “Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa Olódùmarè wí,
10 Èmí yóò yí àsè ẹ̀sìn yín padà sí ọ̀fọ̀,
11 “Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa Olódùmarè wí,
12 Àwọn ènìyàn yóò rìn kiri láti Òkun dé Òkun
13 “Ní ọjọ́ náà
14 Àwọn tí ó fi ẹ̀ṣẹ̀ Samaria búra,