1 Gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ìwọ ilé Israẹli, ìpohùnréré ẹkún tí mo ṣe nípa rẹ:
2 “Wúńdíá Israẹli ṣubú
3 Èyí ni ohun tí Olúwa Olódùmarè wí:
4 Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún ilé Israẹli:
5 ẹ má ṣe wá Beteli,
6 Ẹ wá Olúwa, ẹ̀yin yóò sì yè,
7 Ẹ̀yin tí ẹ̀ sọ òdodo di ìkorò
8 Ẹni tí ó dá ìràwọ̀ Pleiadesi àti Orioni
9 Ó fọ́n ìparun sí ìlú olódi
10 Ìwọ kórìíra ẹni tí ń bá ni wí ní ẹnu ibodè
11 Ìwọ ń tẹ tálákà mọ́lẹ̀
12 Nítorí mo mọ iye àìṣedéédéé rẹ
13 Àwọn ọlọ́gbọ́n máa ń dákẹ́ jẹ́ẹ́ ní àkókò wọ̀nyí,
14 Wá rere, má ṣe wá búburú
15 Kórìíra búburú kí o sì fẹ́ rere
16 Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun wí:
17 Ìpohùnréré ẹkún yóò wà ní gbogbo ọgbà àjàrà,
18 Ègbé ni fún ìwọ tí ó pẹ́
19 Gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí ó sá fún kìnnìún,
20 Ǹjẹ́ ọjọ́ Olúwa kò ha ní ṣókùnkùn dípò kí ó ní ìmọ́lẹ̀?
21 “Mo kórìíra, mo kẹ́gàn àwọn àsè ẹ̀sìn in yín,
22 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ mú ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà wá.
23 Ẹ gbé ariwo orin yín sẹ́yìn!
24 Jẹ́ kí òtítọ́ sàn bí odò
25 “Àbí ẹ̀yin mú ẹbọ àti ọrẹ tọ̀ mí wá
26 Ẹ̀yin ti gbé ibi ìrúbọ àwọn ọba yín sókè,
27 Nítorí náà èmi yóò rán an yín lọ sí ìgbèkùn ní ìkọjá Damasku,”