1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin màlúù Baṣani lórí òkè Samaria,
2 Olúwa Olódùmarè ti fi ìwà mímọ́ rẹ̀ búra:
3 Ẹni kọ̀ọ̀kan yín yóò jáde lọ
4 “Ẹ lọ sí Beteli láti dẹ́ṣẹ̀;
5 Kí ẹ mú ọ̀rẹ́ ìdúpẹ́ ìyẹ̀fun ìwúkàrà ti a sun
6 “Èmi fún un yín ní mímọ́ eyín ní gbogbo ìlú yín,
7 “Àti pẹ̀lú mo mú òjò dúró
8 Àwọn ènìyàn ń rìn láti ìlú kan sí ìlú mìíràn fún omi
9 “Lọ́pọ̀ ìgbà ni mo kọlu ọgbà àti ọgbà àjàrà yín
10 “Mo rán àjàkálẹ̀-ààrùn sí i yín
11 “Mo ti bì ṣubú nínú yín,
12 “Nítorí náà, èyí ni ohun tí èmi yóò ṣe sí i yín, Israẹli,
13 Ẹni tí ó dá àwọn òkè