Amós 2

YOR

1 Èyí ni ohun tí Olúwa wí,

2 Èmi yóò rán iná sí orí Moabu

3 Èmi yóò ké onídàájọ́ rẹ̀ kúrò,

4 Èyí ni ohun tí Olúwa wí,

5 Èmi yóò rán iná sí orí Juda

6 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

7 Wọ́n fi ẹsẹ̀ tẹ orí àwọn tálákà mọ́lẹ̀,

8 Wọ́n dùbúlẹ̀ lẹ́bàá a pẹpẹ,

9 “Mo pa àwọn ará Amori run níwájú wọn

10 Èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá,

11 “Èmi sì tún gbé àwọn wòlíì dìde láàrín àwọn ọmọ yín

12 “Ṣùgbọ́n ẹ̀yin fún àwọn Nasiri ní ọtí mu

13 “Ní báyìí, èmi yóò tẹ̀ yín mọ́lẹ̀

14 Ẹni tí ó yára bí àṣá kò ní rí ọ̀nà àbáyọ

15 Tafàtafà kì yóò dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀

16 Àní jagunjagun tí ó gbóyà jùlọ

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado