1 Àwọn ọ̀rọ̀ Amosi, ọ̀kan lára àwọn olùṣọ́-àgùntàn Tekoa; ohun tí o rí nípa Israẹli ní ọdún méjì ṣáájú ilẹ̀-rírì, nígbà tí Ussiah ọba Juda àti Jeroboamu ọmọ Jehoaṣi jẹ́ ọba ní ilẹ̀ Israẹli.
2 Ó wí pé,
3 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
4 Èmi yóò rán iná sí ilé Hasaeli,
5 Èmi yóò ṣẹ́ ọ̀pá ìdábùú Damasku;
6 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
7 Èmi yóò rán iná sí ara odi Gasa
8 Èmi yóò ké àwọn olùgbé Aṣdodu kúrò,
9 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
10 Èmi yóò rán iná sí ara odi Tire,
11 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
12 Èmi yóò rán iná sí orí Temani,
13 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
14 Èmi yóò rán iná sí ara odi Rabba
15 Ọba wọn yóò sì lọ sí ìgbèkùn,