1 Ẹ béèrè òjò nígbà àrọ̀kúrò ni ọwọ́ Olúwa;
2 Nítorí àwọn òrìṣà tí sọ̀rọ̀ asán,
3 “Ìbínú mi ru sí àwọn darandaran,
4 Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni òkúta igun ilé ti jáde wá,
5 Gbogbo wọn yóò sì dàbí ọkùnrin
6 “Èmi o sì mú ilé Juda ní agbára,
7 Efraimu yóò sì ṣe bí alágbára,
8 Èmi ó kọ sí wọn, èmi ó sì ṣà wọ́n jọ;
9 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo tú wọn káàkiri orílẹ̀-èdè:
10 Èmi ó sì tún mú wọn padà kúrò ni ilẹ̀ Ejibiti pẹ̀lú,
11 Wọn yóò sì la Òkun wàhálà já,
12 Èmi ó sì mú wọn ní agbára nínú Olúwa;