1 Ẹ kọrin tuntun sí Olúwa,
2 Olúwa ti sọ ìgbàlà rẹ̀ di mí mọ̀
3 Ó rántí ìfẹ́ rẹ̀ àti òtítọ́ rẹ̀ fún àwọn ará ilé Israẹli;
4 Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Olúwa, gbogbo ayé,
5 ẹ fi dùùrù kọrin sí Olúwa, pẹ̀lú dùùrù àti ìró ohùn orin mímọ́,
6 pẹ̀lú ìpè àti fèrè
7 Jẹ́ kí òkun kí ó hó pẹ̀lú gbogbo
8 Ẹ jẹ́ kí odo kí ó ṣápẹ́,
9 ẹ jẹ́ kí wọn kọrin níwájú Olúwa,