Salmos 94

YOR

1 Olúwa Ọlọ́run ẹni tí ń gbẹ̀san,

2 Gbé ara rẹ sókè, ìwọ onídàájọ́ ayé;

3 Báwo ní yóò ti pẹ́ tó,

4 Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga jáde;

5 Wọ́n fọ́ àwọn ènìyàn rẹ túútúú, Olúwa:

6 Wọ́n pa àwọn opó àti àlejò,

7 Wọ́n sọ pé, “Olúwa kò rí i;

8 Kíyèsi i, ẹ̀yin aláìlóye nínú àwọn ènìyàn;

9 Ẹni tí ó gbin etí, ó lè ṣe aláìgbọ́ bí?

10 Ẹni tí ń bá orílẹ̀-èdè wí, ṣé kò lè tọ́ ni ṣọ́nà bí?

11 Olúwa mọ èrò inú ènìyàn;

12 Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí

13 Ìwọ gbà á kúrò nínú ọjọ́ ibi,

14 Nítorí Olúwa kò ní kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀,

15 Ìdájọ́ yóò padà sí òdodo,

16 Ta ni yóò dìde fún mi

17 Bí kò ṣe pé Olúwa fún mi ní ìrànlọ́wọ́,

18 Nígbà tí mo sọ pé, “Ẹsẹ̀ mi ń yọ̀”,

19 Nígbà tí àníyàn ńlá wà nínú mi,

20 Ìjọba ìbàjẹ́ ha lè kẹ́gbẹ́ pẹ̀lú rẹ

21 Wọ́n kó ara wọn jọ sí olódodo

22 Ṣùgbọ́n, Olúwa ti di odi alágbára mi,

23 Òun yóò san ẹ̀san ibi wọn fún wọn

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado