Salmos 52

YOR

1 Èéṣe tí ìwọ fi ń ṣe féfé nínú ìwà ìkà, ìwọ alágbára ọkùnrin?

2 Ahọ́n rẹ̀ ń gbìmọ̀ ìparun;

3 Ìwọ fẹ́ràn ibi ju ìre lọ,

4 Ìwọ fẹ́ràn ọ̀rọ̀ ìpanilára gbogbo,

5 Ọlọ́run yóò sì lù ọ́ bolẹ̀ láéláé,

6 Àwọn olódodo yóò rí, wọn yóò sì bẹ̀rù

7 “Èyí ni ọkùnrin náà ti kò fi Ọlọ́run ṣe agbára rẹ̀,

8 Ṣùgbọ́n èmi dàbí igi Olifi

9 Èmi yóò yìn ọ títí fún ohun tí ó ti ṣe;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado