1 “Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú
2 “Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú
3 Àwọn awalẹ̀ walẹ̀ sí ẹ̀yìn mi:
4 Olódodo ni Olúwa:
5 Kí gbogbo àwọn tí ó kórìíra Sioni kí ó dààmú,
6 Kí wọn kí ó dàbí koríko orí ilẹ̀
7 èyí tí olóko pípa kó kún ọwọ́ rẹ̀:
8 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn tí ń kọjá lọ kò wí pé,