1 Èmi fẹ́ràn Olúwa, nítorí ó gbọ́ ohùn mi;
2 Nítorí ó yí etí rẹ̀ padà sí mi,
3 Okùn ikú yí mi ká,
4 Nígbà náà ni mo ké pe orúkọ Olúwa:
5 Olúwa ní oore-ọ̀fẹ́, ó sì ní òdodo;
6 Olúwa pa àwọn ọlọ́kàn fífúyẹ́ mọ́
7 Padà, ìwọ ọkàn mi, sí ibi ìsinmi rẹ,
8 Nítorí ìwọ, Olúwa, ti gba ọkàn mi
9 nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa
10 Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé,
11 Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé,
12 Kí ni èmi yóò san fún Olúwa
13 Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè
14 Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwa
15 Iyebíye ní ojú Olúwa
16 Olúwa, nítòótọ́ ìránṣẹ́ rẹ ni mo jẹ́;
17 Èmi yóò rú ẹbọ ọpẹ́ sí ọ
18 Èmi yóò mú ìlérí mi sẹ sí Olúwa
19 nínú àgbàlá ilé Olúwa