Sofonias 3

YOR

1 Ègbé ni fún ìlú aninilára,

2 Òun kò gbọ́rọ̀ sí ẹnikẹ́ni,

3 Àwọn olórí rẹ̀ jẹ́ kìnnìún tí ń ké ramúramù,

4 Àwọn wòlíì rẹ̀ gbéraga,

5 Olúwa ni àárín rẹ̀ jẹ́ olódodo;

6 “Èmi ti ké àwọn orílẹ̀-èdè kúrò,

7 Èmi wí fún ìlú náà wí pé,

8 Nítorí náà ẹ dúró dè mí,” ni Olúwa wí,

9 “Nígbà náà ni èmi yóò yí èdè àwọn ènìyàn padà sí èdè mímọ́,

10 Láti òkè odò Etiopia,

11 Ní ọjọ́ náà ni a kì yóò sì dójútì

12 Ṣùgbọ́n Èmi yóò fi àwọn ọlọ́kàn tútù

13 Àwọn ìyókù Israẹli kì yóò hùwà ibi,

14 Kọrin, ìwọ ọmọbìnrin Sioni,

15 Olúwa ti mú ìdájọ́ rẹ wọ̀n-ọn-nì kúrò,

16 Ní ọjọ́ náà, wọn yóò sọ fún Jerusalẹmu pé,

17 Olúwa Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,

18 “Èmi ó kó àwọn tí ó ń banújẹ́ fún àjọ̀dún tí a yàn jọ,

19 Ní àkókò náà

20 Ní àkókò náà ni èmi yóò ṣà yín jọ;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado