Oséias 7

YOR

1 nígbà tí èmi ìbá mú Israẹli láradá.

2 ṣùgbọ́n wọn kò mọ̀ pé

3 “Wọ́n ń mú inú ọba dùn pẹ̀lú ìwà búburú wọn,

4 Alágbèrè ni gbogbo wọn

5 Ní ọjọ́ àjọ̀dún ọba wa

6 Ọkàn wọn ń gbóná bí i ààrò

7 Gbogbo wọn gbóná bí ààrò

8 “Efraimu ti darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn náà;

9 Àwọn àlejò ti jẹ agbára rẹ̀ run

10 Ìgbéraga Israẹli ń jẹ́rìí sí i

11 “Efraimu dàbí àdàbà

12 Nígbà tí wọ́n bá lọ, èmi ó ta àwọ̀n mi sórí wọn,

13 Ègbé ní fún wọn,

14 Wọn kò kégbe pè mí láti ọkàn wọn,

15 Mo kọ́ wọn, mo sì fún wọn ní agbára,

16 Wọn kò padà sí ọ̀dọ̀ Ọ̀gá-ògo;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado