Jó 12

YOR

1 Jobu sì dáhùn, ó sì wí pé,

2 “Kò sí àní àní níbẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀yin ni àwọn ènìyàn náà,

3 Ṣùgbọ́n èmi ní ìyè nínú gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin;

4 “Èmi dàbí ẹni tí a ń fi ṣe ẹlẹ́yà lọ́dọ̀ aládùúgbò rẹ̀,

5 Ó rọrùn fún ènìyàn láti fi ìbànújẹ́ ẹlòmíràn ṣe ẹlẹ́yà

6 Àgọ́ àwọn ìgárá ọlọ́ṣà wá láìní ìbẹ̀rù;

7 “Ṣùgbọ́n nísinsin yìí bí àwọn ẹranko léèrè, wọn o kọ́ ọ ní ẹ̀kọ́,

8 Tàbí ba ilẹ̀ ayé sọ̀rọ̀, yóò sì kọ́ ọ,

9 Ta ni kò mọ̀ nínú gbogbo nǹkan wọ̀nyí pé,

10 Ní ọwọ́ ẹni tí ẹ̀mí ohun alààyè gbogbo gbé wà,

11 Etí kì í dán ọ̀rọ̀ wò bí

12 Àwọn arúgbó ni ọgbọ́n wà fún,

13 “Ti Ọlọ́run ni ọgbọ́n àti agbára;

14 Kíyèsi i, ó bì wó, a kò sì lè gbe ró mọ́;

15 Kíyèsi i, ó dá àwọn omi dúró, wọ́n sì gbẹ;

16 Tìrẹ ni agbára àti ìṣẹ́gun;

17 Ó mú àwọn ìgbìmọ̀ lọ ní ìhòhò

18 Ó tú ìdè ọba

19 Ó mú àwọn àlùfáà lọ ní ìhòhò

20 Ó mú ọ̀rọ̀ ẹnu ẹni ìgbẹ́kẹ̀lé kúrò

21 Ó bu ẹ̀gàn lu àwọn ọmọ ọlọ́lá

22 Ó hú ìdí ohun ìjìnlẹ̀ jáde láti inú òkùnkùn wá

23 Òun a mú orílẹ̀-èdè bí sí i, a sì run wọ́n;

24 Òun a gba òye àwọn olórí àwọn ènìyàn aráyé,

25 Wọn a máa fi ọwọ́ ta ilẹ̀ nínú òkùnkùn níbi tí kò sí ìmọ́lẹ̀;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado