Jó 10

YOR

1 “Agara ìwà ayé mi dá mi tán;

2 Èmi yóò wí fún Ọlọ́run pé, má ṣe dá mi lẹ́bi;

3 Ó ha tọ́ tí ìwọ ìbá fi máa ni mí lára,

4 Ojú rẹ kì ha ṣe ojú ènìyàn bí?

5 Ọjọ́ rẹ ha dàbí ọjọ́ ènìyàn,

6 tí ìwọ fi ń béèrè àìṣedéédéé mi,

7 Ìwọ mọ̀ pé èmi kì í ṣe oníwà búburú,

8 “Ọwọ́ rẹ ni ó mọ mi, tí ó sì da mi.

9 Èmi bẹ̀ ọ́ rántí pé ìwọ ti mọ mí bí amọ̀.

10 Ìwọ kò ha ti tú mí dà jáde bí i wàrà,

11 Ìwọ sá ti fi àwọ̀ ẹran-ara wọ̀ mí,

12 Ìwọ ti fún mi ní ẹ̀mí àti ojúrere,

13 “Nǹkan wọ̀nyí ni ìwọ sì ti fi pamọ́ nínú rẹ;

14 Bí mo bá ṣẹ̀, nígbà náà ni ìwọ yóò máa ṣọ́ mi

15 Bí mo bá ṣe ẹni búburú, ègbé ni fún mi!

16 Bí mo bá gbé orí mi ga, ìwọ ń dẹ mí kiri bi i kìnnìún

17 Ìwọ sì tún mu àwọn ẹlẹ́rìí rẹ dìde sí mi di ọ̀tún

18 “Nítorí kí ni ìwọ ṣe mú mi jáde láti inú wá?

19 Tí kò bá le jẹ́ pé èmi wà láààyè,

20 Ọjọ́ mi kò ha kúrú bí? Rárá!

21 Kí èmi kí ó tó lọ sí ibi tí èmi kì yóò padà sẹ́yìn mọ́,

22 ilẹ̀ òkùnkùn bí òkùnkùn tìkára rẹ̀,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado