Isaías 3

YOR

1 Kíyèsi i, Olúwa,

2 Àwọn akíkanjú àti jagunjagun,

3 balógun àádọ́ta àti àwọn ènìyàn, onípò gíga;

4 “Èmi ó sọ àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin di aláṣẹ wọn,

5 Àwọn ènìyàn yóò sì máa pọ́n ọmọnìkejì,

6 Ọkùnrin kan yóò di ọ̀kan nínú àwọn

7 Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ náà ni yóò figbe bọnu pé,

8 Jerusalẹmu ń ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n

9 Ìwò ojú wọn ń jẹ́rìí lòdì sí wọn,

10 Ẹ sọ fún olódodo pé yóò dára fún wọn,

11 Ègbé ni fún ènìyàn búburú! Ìparun wà lórí i wọn,

12 Àwọn ọ̀dọ́mọdé ni o ń pọ́n àwọn ènìyàn mi lójú

13 Olúwa bọ sí ipò rẹ̀ ní ìtẹ́ ìdájọ́

14 Olúwa dojú ẹjọ́ kọ

15 Kín ni èrò yín láti máa run àwọn ènìyàn mi túútúú

16 Olúwa wí pé,

17 Nítorí náà Olúwa yóò mú egbò wá sórí àwọn obìnrin Sioni,

18 Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò já ọ̀ṣọ́ wọn gbà kúrò ti ọwọ́ àti gèlè àti ẹ̀gbà ọrùn tí ó dàbí òṣùpá

19 gbogbo yẹtí, ẹ̀gbà ọwọ́ àti ìbòjú,

20 gbogbo gèlè, ẹ̀gbà ọrùn, ẹsẹ̀ àti àyà, àwọn ìgò tùràrí àti òògùn,

21 òrùka ọwọ́ àti ti imú,

22 àwọn àtàtà aṣọ, àwọ̀lékè, agbádá àti àpamọ́wọ́,

23 dígí wọn, aṣọ funfun nigínnigín ìbòrí àti ìbòjú.

24 Dípò òórùn dídùn, òórùn búburú ni yóò wá,

25 Àwọn ọkùnrin rẹ yóò ti ipa idà ṣubú,

26 Àwọn bodè Sioni yóò sọkún kíkorò, wọn ó ṣọ̀fọ̀,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado