Isaías 26

YOR

1 Ní ọjọ́ náà ni a ó kọ orin yìí ní ilẹ̀ Juda.

2 Ṣí àwọn ìlẹ̀kùn

3 Ìwọ yóò pa á mọ́ ní àlàáfíà pípé

4 Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa títí láé,

5 Ó sọ àwọn tí ó ń gbé ní òkè di onírẹ̀lẹ̀

6 Ẹsẹ̀ tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀

7 Ipa ọ̀nà àwọn olódodo tẹ́jú,

8 Bẹ́ẹ̀ ni, Olúwa, rírìn ní ọ̀nà òfin rẹ

9 Ọkàn mi ń pòùngbẹẹ̀ rẹ ní ọ̀gànjọ́ òru;

10 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a fi oore-ọ̀fẹ́ hàn sí àwọn ìkà

11 Olúwa, ti gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè

12 Olúwa, ìwọ fi àlàáfíà lélẹ̀ fún wa;

13 Olúwa Ọlọ́run wa, àwọn olúwa mìíràn

14 Wọ́n ti kú báyìí, wọn ò sí láààyè mọ́;

15 Ìwọ ti mú orílẹ̀-èdè gbòòrò, Olúwa;

16 Olúwa, wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ nínú ìpọ́njú wọn;

17 Gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó lóyún tí ó sì fẹ́rẹ̀ bímọ

18 Àwa wà nínú oyún, a wà nínú ìrora,

19 Ṣùgbọ́n àwọn òkú yín yóò wà láààyè

20 Ẹ lọ, ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ wọ ìyẹ̀wù yín lọ

21 Kíyèsi i, Olúwa ń jáde bọ̀ láti ibùgbé rẹ̀

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado