1 Olúwa yóò fi àánú hàn fún Jakọbu,
2 Àwọn orílẹ̀-èdè yóò gbà wọ́n
3 Ní ọjọ́ tí Olúwa yóò fi ìtura fún un yín kúrò nínú ìpọ́njú àti ìyà àti ìdè ìkà,
4 ẹ ó sì fi ọ̀rọ̀ àbùkù yìí kan ọba Babeli pé,
5 Olúwa ti dá ọ̀pá ìkà náà,
6 èyí tí ó ti lu àwọn ènìyàn bolẹ̀
7 Gbogbo ilẹ̀ ni ó wà ní ìsinmi àti àlàáfíà,
8 Pẹ̀lúpẹ̀lú àwọn igi junifa àti àwọn
9 Ibojì tí ó wà ní ìsàlẹ̀ ni a ru sókè
10 Gbogbo wọn yóò dáhùn,
11 Gbogbo rẹ̀ ni ó di ìrẹ̀sílẹ̀ lọ sí ibojì,
12 Báwo ni ìwọ ṣe ṣubú lulẹ̀ láti ọ̀run wá,
13 Ìwọ sọ nínú ọkàn rẹ pé,
14 Èmi yóò gòkè lọ rékọjá àwọn àwọsánmọ̀;
15 Ṣùgbọ́n a ti rẹ̀ ọ́ sílẹ̀ wọ inú ibojì lọ
16 Àwọn tí ó rí ọ yóò tẹjúmọ́ ọ,
17 Ẹni tí ó sọ ayé di aginjù,
18 Gbogbo àwọn ọba orílẹ̀-èdè ni a tẹ́ sílẹ̀
19 Ṣùgbọ́n a jù ọ́ síta kúrò nínú ibojì
20 a kò ní sin ọ́ pẹ̀lú wọn,
21 Tọ́jú ibìkan tí a ó ti pa àwọn ọmọkùnrin rẹ
22 “Èmi yóò dìde sókè sí wọn,”
23 Èmi yóò yí i padà sí ibùgbé àwọn òwìwí
24 Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti búra,
25 Èmi yóò run Asiria ní ilẹ̀ mi,
26 Èyí ni ètò tí a pinnu rẹ̀ fún gbogbo ayé,
27 Nítorí Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti pète,
28 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ yí wá ní ọdún tí ọba Ahasi kú.
29 Má ṣe yọ̀, gbogbo ẹ̀yin Filistia,
30 Ẹni tí ó kúṣẹ̀ẹ́ jù yóò ní pápá oko,
31 Hu, ìwọ ẹnu-ọ̀nà! Kígbe, ìwọ ìlú!
32 Kí ni ìdáhùn tí a ó fún