1 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Babeli èyí tí Isaiah ọmọ Amosi rí.
2 Gbé àsíá sókè ní orí òkè gbẹrẹfu,
3 Mo ti pàṣẹ fún àwọn ẹni mímọ́ mi,
4 Gbọ́ ohùn kan ní àwọn orí òkè,
5 Wọ́n wá láti ọ̀nà jíjìn réré,
6 Ẹ hu, nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ tòsí,
7 Nítorí èyí, gbogbo ọwọ́ ni yóò rọ,
8 Ẹ̀rù yóò gbá wọn mú,
9 Kíyèsi i, ọjọ́ Olúwa ń bọ̀
10 Àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti ìkójọpọ̀ wọn
11 Èmi yóò jẹ ayé ní ìyà nítorí ibi rẹ̀,
12 Èmi yóò jẹ́ kí ọkùnrin kí ó wọn
13 Nítorí náà èmi yóò jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó wárìrì;
14 Gẹ́gẹ́ bí egbin tí à ń dọdẹ rẹ̀,
15 Ẹnikẹ́ni tí a bá gbámú ni a ó wọ́ nílẹ̀ tuurutu,
16 Àwọn ọ̀dọ́mọdé wọn ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ níṣojú wọn,
17 Kíyèsi i, èmi yóò ru àwọn Media sókè sí wọn,
18 Ọrùn wọn yóò ré àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin lulẹ̀;
19 Babeli, ohun ọ̀ṣọ́ àwọn ìjọba
20 A kì yóò tẹ̀ ibẹ̀ dó mọ́
21 Ṣùgbọ́n àwọn ẹranko igbó ni yóò dùbúlẹ̀ níbẹ̀,
22 Ìkookò yóò máa gbó ní ibùba wọn,