Isaías 11

YOR

1 Èèkàn kan yóò sọ láti ibi kùkùté Jese,

2 Ẹ̀mí Olúwa yóò sì bà lé e,

3 Òun yóò sì ní inú dídùn nínú ìbẹ̀rù Olúwa.

4 ṣùgbọ́n pẹ̀lú òdodo ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn aláìní,

5 Òdodo ni yóò jẹ́ ìgbànú rẹ̀

6 Ìkookò yóò sì máa bá ọmọ àgùntàn gbé,

7 Màlúù àti beari yóò máa jẹun pọ̀,

8 Ọ̀dọ́mọdé yóò ṣeré lẹ́bàá ihò ọká,

9 Wọn kò ní ṣe ni léṣe tàbí pa ni run

10 Ní ọjọ́ náà, gbòǹgbò Jese yóò dúró gẹ́gẹ́ bí àsíá fún gbogbo ènìyàn, àwọn orílẹ̀-èdè yóò pagbo yí i ká, ibùdó ìsinmi rẹ̀ yóò jẹ́ èyí tí ó lógo.

11 Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò na ọwọ́ rẹ̀ jáde nígbà kejì láti tún gba àwọn tí ó ṣẹ́kù àní àwọn tí a ṣẹ́kù nínú àwọn ènìyàn an rẹ̀ láti Asiria wá, láti ìsàlẹ̀ Ejibiti àti òkè Ejibiti, láti Kuṣi, láti Elamu láti Babiloni, láti Hamati àti láti àwọn erékùṣù inú Òkun.

12 Òun yóò gbé àsíá sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè,

13 Owú jíjẹ Efraimu yóò pòórá,

14 Wọn yóò fò mọ́ èjìká Filistini

15 Olúwa yóò sọ di gbígbé

16 Ọ̀nà gidi yóò wà fún àwọn ènìyàn an rẹ̀ tí ó ṣẹ́kù

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado