1 Gẹ́gẹ́ bí òkú eṣinṣin tí ń fún òróró ìkunra ní òórùn búburú,
2 Ọkàn ọlọ́gbọ́n a máa ṣí sí ohun tí ó tọ̀nà,
3 Kódà bí ó ti ṣe ń rìn láàrín ọ̀nà,
4 Bí ìbínú alákòóso bá dìde lòdì sí ọ,
5 Ohun ibi kan wà tí mo ti rí lábẹ́ oòrùn,
6 A gbé aṣiwèrè sí ọ̀pọ̀ ipò tí ó ga jùlọ,
7 Mo ti rí ẹrú lórí ẹṣin,
8 Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ó le è ṣubú sínú rẹ̀;
9 Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbe òkúta le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn;
10 Bí àáké bá kú
11 Bí ejò bá ṣán ni kí a tó lo oògùn rẹ̀,
12 Ọ̀rọ̀ tí ó wá láti ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa ní oore-ọ̀fẹ́
13 Ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ́ òmùgọ̀;
14 Wèrè a sì máa ṣàfikún ọ̀rọ̀.
15 Iṣẹ́ aṣiwèrè a máa dá a lágara
16 Ègbé ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ tí ọba ń ṣe ìránṣẹ́ rẹ̀
17 Ìbùkún ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ èyí tí ọba rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọlọ́lá,
18 Bí ènìyàn bá ń lọ́ra, àjà ilé a máa jì
19 Ẹ̀rín rínrín ni a ṣe àsè fún,
20 Ma ṣe bú ọba, kódà nínú èrò rẹ,