Cânticos 2

YOR

1 Èmi ni ìtànná Ṣaroni

2 Bí ìtànná lílì ní àárín ẹ̀gún

3 Bí igi ápù láàrín àwọn igi inú igbó,

4 Ó mú mi lọ sí ibi gbọ̀ngàn àsè,

5 Fi agbára adùn àkàrà dá mi dúró.

6 Ọwọ́ òsì rẹ ń bẹ lábẹ́ orí mi

7 Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerusalẹmu,

8 Gbọ́ ohùn olùfẹ́ mi!

9 Olùfẹ́ mi dàbí abo egbin tàbí ọmọ àgbọ̀nrín.

10 Olùfẹ́ mi fọhùn ó sì sọ fún mi pé,

11 Wò ó! Ìgbà òtútù ti kọjá;

12 Àwọn òdòdó fi ara hàn lórí ilẹ̀

13 Igi ọ̀pọ̀tọ́ mú èso tuntun jáde,

14 Àdàbà mi wà nínú pàlàpálá òkúta,

15 Bá wa mú àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀,

16 Olùfẹ́ mi ni tèmi èmi sì ni tirẹ̀;

17 Títí ìgbà ìtura ọjọ́

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado