1 Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dafidi tí a bí fún un ní Hebroni.
2 ẹ̀kẹta sì ni Absalomu ọmọ Maaka ọmọbìnrin Talmai ọba Geṣuri bí fún un;
3 ẹ̀karùnún ni Ṣefatia láti ọ̀dọ̀ Abitali;
4 Àwọn mẹ́fà wọ̀nyí ni a bí fún Dafidi ni Hebroni, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà.
5 Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu:
6 Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti,
7 Noga, Nefegi, Jafia,
8 Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n.
9 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn.
10 Ọmọ Solomoni ni Rehoboamu,
11 Jehoramu ọmọ rẹ̀,
12 Amasiah ọmọ rẹ̀,
13 Ahasi ọmọ rẹ̀,
14 Amoni ọmọ rẹ̀,
15 Àwọn ọmọ Josiah:
16 Àwọn ìran ọmọ Jehoiakimu:
17 Àwọn ọmọ Jekoniah tí a mú ní ìgbèkùn:
18 Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah.
19 Àwọn ọmọ Pedaiah:
20 Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi.
21 Àwọn ọmọ Hananiah:
22 Àwọn ọmọ Ṣekaniah:
23 Àwọn ọmọ Neariah:
24 Àwọn ọmọ Elioenai: