Salmos 132

YOR

1 Olúwa, rántí Dafidi

2 Ẹni tí ó ti búra fún Olúwa,

3 Nítòótọ́, èmi kì yóò wọ inú àgọ́ ilé mi lọ,

4 Èmi kì yóò fi oorun fún ojú mi,

5 títí èmi ó fi rí ibi fún Olúwa,

6 Kíyèsi i, àwa gbúròó rẹ̀ ni Efrata:

7 Àwa ó lọ sínú àgọ́ rẹ̀:

8 Olúwa, dìde sí ibi ìsinmi rẹ:

9 Kí a fi òdodo wọ àwọn àlùfáà rẹ:

10 Nítorí tí Dafidi ìránṣẹ́ rẹ̀,

11 Olúwa ti búra nítòótọ́ fún Dafidi,

12 Bí àwọn ọmọ rẹ̀ yóò bá pa májẹ̀mú mi mọ́

13 Nítorí tí Olúwa ti yan Sioni:

14 Èyí ni ibi ìsinmi mi láéláé:

15 Èmi yóò bùkún oúnjẹ rẹ̀ púpọ̀púpọ̀:

16 Èmi yóò sì fi ìgbàlà wọ àwọn àlùfáà rẹ̀:

17 Níbẹ̀ ni èmi yóò gbé mú ìwo Dafidi yọ̀,

18 Àwọn ọ̀tá rẹ̀ ni èmi yóò fi ìtìjú wọ̀:

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado