Juízes 5

YOR

1 Nígbà náà ni Debora àti Baraki ọmọ Abinoamu kọ orin ní ọjọ́ náà wí pé,

2 “Nítorí bí àwọn olórí ti síwájú ní Israẹli,

3 “Ẹ gbọ́ ẹ̀yin ọba! Ẹ fetí yín sílẹ̀ ẹ̀yin ọmọ-aládé!

4 “Olúwa nígbà tí o jáde kúrò ní Seiri,

5 Àwọn òkè ńlá wárìrì ní iwájú Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni Sinai ní iwájú Olúwa

6 “Ní ọjọ́ Ṣamgari ọmọ Anati,

7 Àwọn olórí tán ní Israẹli,

8 Wọ́n ti yan ọlọ́run tuntun,

9 Àyà mi fà sí àwọn aláṣẹ Israẹli

10 “Ẹ kéde rẹ̀: ẹ̀yin tí ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ funfun,

11 ariwo àwọn tafàtafà, ní ibi tí a gbé ń fa omi.

12 ‘Jí, jí, Debora!

13 “Nígbà náà ni àwọn tókù sọ̀kalẹ̀ àwọn ọlọ́lá lọ;

14 Àwọn kan jáde wá láti Efraimu, àwọn tí gbòǹgbò wọn wà ní Amaleki;

15 Àwọn ọmọ-aládé Isakari wá pẹ̀lú Debora;

16 Èéṣe tí ìwọ fi dúró pẹ́ láàrín agbo àgùntàn

17 Gileadi dúró ní òkè odò Jordani.

18 Àwọn ènìyàn Sebuluni fi ẹ̀mí wọn wéwu ikú;

19 “Àwọn ọba wá, wọ́n sì jà;

20 Àwọn ìràwọ̀ já láti ojú ọ̀run wá

21 Odò Kiṣoni gbá wọn lọ,

22 Nígbà náà ni pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin ki ilẹ̀,

23 ‘Ẹ fi Merosi bú,’ ni angẹli Olúwa wí.

24 “Ìbùkún ni fún Jaeli,

25 Ó béèrè omi, ó fún un ní wàrà;

26 Ó na ọwọ́ rẹ̀ mú ìṣó àgọ́,

27 Ní ẹsẹ̀ rẹ̀ ó wólẹ̀,

28 “Ìyá Sisera yọjú láti ojú fèrèsé,

29 Àwọn amòye obìnrin rẹ̀ dá a lóhùn;

30 ‘Wọn kò ha ń wa kiri, wọn kò ha ti pín ìkógun bi:

31 “Bẹ́ẹ̀ ni kí ó jẹ́ kí gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kí ó ṣègbé Olúwa!

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado