Jeremias 15

YOR

1 Nígbà náà ni Olúwa sọ fún mi pé: “Kódà kí Mose àti Samuẹli dúró níwájú mi, ọkàn mi kì yóò lọ sọ́dọ̀ àwọn ènìyàn wọ̀nyí. Mú wọn kúrò níwájú mi! Jẹ́ kí wọn ó lọ!

2 Tí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Níbo ni kí a lọ?’ Sọ fún wọn pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí:

3 “Èmi yóò rán oríṣìí ìjìyà mẹ́rin láti kọlù wọ́n,” ni Olúwa wí, “Idà láti pa, àwọn ajá láti wọ́ wọn lọ, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ẹranko orí ilẹ̀ láti jẹ àti láti parun.

4 N ó sọ wọ́n di ẹni ìkórìíra níwájú gbogbo ìjọba ayé torí ohun tí Manase ọmọ Hesekiah ọba Juda ṣe ní Jerusalẹmu.

5 “Ta ni yóò ṣàánú rẹ, ìwọ Jerusalẹmu?

6 O ti kọ̀ mí sílẹ̀,” ni Olúwa wí,

7 Èmi kò tún lè fi ìfẹ́ hàn si ọ,

8 Èmi yóò jẹ́ kí àwọn opó wọn pọ̀ ju

9 Ìyá ọlọ́mọ méje yóò dákú,

10 Háà! Ó ṣe tí ìyá mi bí mi,

11 Olúwa sọ pé,

12 “Ǹjẹ́ ẹnìkan lè fi ọwọ́ ṣẹ́ irin

13 “Gbogbo ọlá àti ìṣúra rẹ

14 Èmi yóò fi ọ́ ṣẹrú fún àwọn ọ̀tá rẹ

15 Ó yé ọ, ìwọ Olúwa;

16 Nígbà tí ọ̀rọ̀ rẹ dé, mo jẹ wọ́n,

17 Èmi kò fìgbà kan jókòó láàrín àwọn ẹlẹ́gàn,

18 Èéṣe tí ìrora mi kò lópin,

19 Nítorí náà báyìí ni Olúwa wí,

20 Èmi fi ọ́ ṣe odi idẹ tí ó lágbára,

21 “Èmi yóò gbà ọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ìkà ènìyàn,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado