Jó 28

YOR

1 Nítòótọ́, koto fàdákà ń bẹ,

2 Nínú ilẹ̀ ni à ń gbé ń wa irin,

3 Ènìyàn ni ó fi òpin si òkùnkùn,

4 Wọ́n wa ihò ilẹ̀ tí ó jì sí àwọn tí ń gbé òkè,

5 Bí ó ṣe ti ilẹ̀ ni, nínú rẹ̀ ni oúnjẹ ti ń jáde wá,

6 òkúta ibẹ̀ ni ibi òkúta safire,

7 Ipa ọ̀nà náà ni ẹyẹ kò mọ̀,

8 Àwọn ẹranko agbéraga kò rìn ibẹ̀ rí,

9 Ó fi ọwọ́ rẹ̀ lé akọ òkúta,

10 Ó sì la ipa odò ṣíṣàn nínú àpáta,

11 Ó sì ṣe ìṣàn odò kí ó má ṣe kún àkúnya,

12 Ṣùgbọ́n níbo ni á ó gbé wá ọgbọ́n rí,

13 Ènìyàn kò mọ iye rẹ̀,

14 Ọ̀gbun wí pé, “Kò sí nínú mi”;

15 A kò le è fi wúrà rà á,

16 A kò le è fi wúrà Ofiri, tàbí òkúta óníkìsì iyebíye,

17 Wúrà àti òkúta kristali kò tó ẹgbẹ́ rẹ̀;

18 A kò lè dárúkọ iyùn tàbí òkúta jasperi;

19 Òkúta topasi ti Kuṣi kò tó ẹgbẹ́ rẹ̀;

20 Níbo ha ni ọgbọ́n ti jáde wá?

21 A rí i pé, ó fi ara sinko kúrò ní ojú àwọn alààyè gbogbo,

22 Ibi ìparun àti ikú wí pé,

23 Ọlọ́run ni ó mọ òye ipa ọ̀nà rẹ̀,

24 Nítorí pé ó wòye dé òpin ayé,

25 láti dà òsùwọ̀n fún afẹ́fẹ́,

26 Nígbà tí ó pàṣẹ fún òjò,

27 nígbà náà ni ó rí i, ó sì sọ ọ́ jáde;

28 Àti fún ènìyàn ni ó wí pé,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado