Ezequiel 28

YOR

1 Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé:

2 “Ọmọ ènìyàn, sọ fún ọmọ-aládé Tire pé, ‘Báyìí ní Olúwa Olódùmarè wí:

3 Ìwọ gbọ́n ju Daniẹli lọ bí?

4 Pẹ̀lú ọgbọ́n àti ìmọ̀ rẹ,

5 Nípa ọgbọ́n rẹ ńlá àti nípa òwò rẹ,

6 “ ‘Nítorí náà èyí yìí ní Olúwa Olódùmarè wí:

7 Èmi yóò mú kí àwọn àjèjì dìde sí ọ,

8 Wọn yóò mú ọ sọ̀kalẹ̀ wá sínú ihò,

9 Ṣé ìwọ yóò wá wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run,”

10 Ìwọ yóò kú ikú aláìkọlà,

11 Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé:

12 “Ọmọ ènìyàn, pohùnréré ẹkún sórí ọba Tire kí ó sì sọ fún un pé: ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa Olódùmarè wí:

13 Ìwọ ti wà ní Edeni, ọgbà Ọlọ́run;

14 A fi àmì òróró yàn ọ́ gẹ́gẹ́ bí olùtọ́jú kérúbù,

15 Ìwọ pé ní ọ̀nà rẹ,

16 Nípa ìtànkálẹ̀ òwò rẹ,

17 Ọkàn rẹ gbéraga,

18 Nípa ẹ̀ṣẹ̀ púpọ̀ rẹ àti òwò àìṣòótọ́ rẹ,

19 Gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó mọ̀ ọ́n,

20 Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé:

21 “Ọmọ ènìyàn, kọ ojú sí Sidoni; kí o sì sọtẹ́lẹ̀ sí i,

22 kí ó sì wí pé, ‘Báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí:

23 Èmi yóò sì rán àjàkálẹ̀-ààrùn sínú rẹ,

24 “ ‘Kì yóò sì ṣí ẹ̀gún tí ń gun ni ní ilẹ̀ Israẹli mọ́, tàbí ẹ̀gún bíbani nínú jẹ́ ti gbogbo àwọn tí wọn wà ní àyíká wọn, tí wọ́n sì ń fi ojú yẹpẹrẹ wò wọ́n, nígbà náà ni wọn yóò mọ́ wí pé èmi ni Olúwa Olódùmarè.

25 “ ‘Èyí yìí ní Olúwa Olódùmarè wí: Nígbà tí èmi yóò bá sa àwọn ènìyàn Israẹli jọ kúrò ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti fọ́nká sí, tí a ó sì yà mí sí mímọ́ láàrín wọn lójú àwọn aláìkọlà. Nígbà náà ni wọn yóò gbé ní ilẹ̀ àwọn tìkálára wọn, èyí tí mo fún ìránṣẹ́ mi Jakọbu.

26 Wọn yóò sì máa gbé ní inú rẹ̀ ní àìléwu, wọn yóò sì kọ́lé, wọn yóò sì gbin ọgbà àjàrà; nítòótọ́ wọn yóò wà ní ìbàlẹ̀ àyà, nígbà tí èmi bá ti mú ìdájọ́ mi ṣẹ̀ sí ara àwọn tí ń ṣátá wọn ní gbogbo àyíká wọn. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé, Èmi ni Olúwa Ọlọ́run wọn.’ ”

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado