1 Dafidi sì kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sí Olúwa ní ọjọ́ tí Olúwa gbà á kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀, àti kúrò lọ́wọ́ Saulu.
2 Ó sì wí pé,
3 Ọlọ́run mi, àpáta mi, nínú ẹni tí èmi ní ààbò,
4 “Èmi ké pe Olúwa, tí ó yẹ láti máa yìn,
5 Nígbà tí ìbìlù ìrora ikú yí mi káàkiri;
6 Ọ̀já isà òkú yí mi káàkiri;
7 “Nínú ìpọ́njú mi, èmi ké pé Olúwa,
8 Ilẹ̀ sì mì, ó sì wárìrì;
9 Èéfín ti ihò imú rẹ̀ jáde wá,
10 Ó tẹ orí ọ̀run ba pẹ̀lú, ó sì sọ̀kalẹ̀;
11 Ó sì gun orí kérúbù, ó sì fò,
12 Ó sì fi òkùnkùn ṣe ibùjókòó yí ara rẹ̀, àti àgbájọ omi,
13 Nípasẹ̀ ìmọ́lẹ̀ iwájú rẹ̀
14 Olúwa sán àrá láti ọ̀run wá,
15 Ó sì ta ọfà, ó sì tú wọn ká;
16 Ìṣàn ibú òkun sì fi ara hàn,
17 “Ó ránṣẹ́ láti òkè wá, ó mú mi;
18 Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi alágbára,
19 Wọ́n wá láti borí mi lọ́jọ́ ìpọ́njú mi,
20 Ó sì mú mi wá sí ààyè ńlá,
21 “Olúwa sán án fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi;
22 Nítorí pé èmi pa ọ̀nà Olúwa mọ́,
23 Nítorí pé gbogbo ìdájọ́ rẹ̀ ni ó wà níwájú mi;
24 Èmi sì wà nínú ìwà títọ́ sí í,
25 Olúwa sì san fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi,
26 “Fún aláàánú ni ìwọ ó fi ara rẹ̀ hàn ni aláàánú,
27 Fún onínú funfun ni ìwọ fi ara rẹ hàn ní funfun;
28 Àwọn ènìyàn tí ó wà nínú ìyà ni ìwọ ó sì gbàlà;
29 Nítorí ìwọ ni ìmọ́lẹ̀ mi, Olúwa;
30 Bẹ́ẹ̀ ni nítorí nípa rẹ̀ ni èmi ti la àárín ogun kọjá;
31 “Ọlọ́run yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀;
32 Nítorí ta ni Ọlọ́run, bí kò ṣe Olúwa?
33 Ọlọ́run alágbára ni ó fún mi ní agbára,
34 Ó ṣe ẹsẹ̀ mi bí ẹsẹ̀ abo àgbọ̀nrín;
35 Ó kọ́ ọwọ́ mi ní ogun jíjà;
36 Ìwọ sì ti fún mi ní asà ìgbàlà rẹ̀;
37 Ìwọ sì sọ ìtẹ̀lẹ̀ di ńlá ní abẹ́ mi;
38 “Èmi ti lépa àwọn ọ̀tá mi, èmi sì ti run wọ́n,
39 Èmi ti pa wọ́n run, èmi sì ti fọ́ wọn,
40 Ìwọ sì ti fi agbára dì mí ní àmùrè fún ìjà;
41 Ìwọ sì mú àwọn ọ̀tá mi pẹ̀yìndà fún mi,
42 Wọ́n wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan láti gbà wọ́n;
43 Nígbà náà ni èmi sì gún wọn wẹ́wẹ́ bí erùpẹ̀ ilẹ̀,
44 “Ìwọ sì gbà mí kúrò lọ́wọ́ ìjà àwọn ènìyàn mi,
45 Àwọn àjèjì wá láti tẹríba fún mi;
46 Àyà yóò pá àwọn àlejò,
47 “Olúwa ń bẹ́; olùbùkún sì ni àpáta mi!
48 Ọlọ́run ni ẹni tí ń gbẹ̀san mi,
49 Àti ẹni tí ó gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.
50 Nítorí náà èmi ó fi ọpẹ́ fún ọ, Olúwa,
51 “Òun ni ilé ìṣọ́ ìgbàlà fún ọba rẹ̀;